ONA ỌLỌRUN KURO NINU IROSUN Jóòbù 38:1-10, 40:1-5, 42:1-10; 2 Kọ́ríńtì 5:17 Fílípì 4;4, Hébérù 12:1-3, Lúùkù 23:33, 34 .
“Ìfẹ́” tí ó wà nínú ẹ̀dá ènìyàn dà bí ìkọ̀kọ̀ tí a fi sínú ọkàn gbogbo ènìyàn, Ọlọ́run ti fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní kọ́kọ́rọ́ láti tipa tàbí ṣí i “Ìfẹ́” náà. .