AKSORI : 2Kọrinti 4:1-7 Ẹsẹ iranti : Iṣe 1:8 ; Ṣùgbọ́n ẹ̀yin yíò gba agbára, lẹ́yìn tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá ti bà lé yín; ẹnyin o si jẹ ẹlẹri fun mi ni Jerusalemu, ati ni gbogbo Judea, ati ni Samaria, ati titi de opin ilẹ aiye .