AKSORI : Nigbati nw9n si ti gbadura tan, ibi ti nw9n peju si mi; gbogbo wọn si kún fun Ẹmi Mimọ́, nwọn si sọ̀rọ Ọlọrun pẹlu igboiya. Ati pẹlu agbara nla awọn aposteli jẹri ajinde Jesu Oluwa: ore-ọfẹ nla si wà lara gbogbo wọn. Iṣe 4:31,33