ẸKỌ: Jẹ́nẹ́sísì 39:1-10 ẸSẸ̀ ÌRÁNTÍ: Gálátíà 6:7-8 “Ẹ má ṣe jẹ́ kí a tàn yín jẹ; kórè ìdíbàjẹ́; ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ń fúnrúgbìn sípa Ẹ̀mí yóò ká ìyè àìnípẹ̀kun nípasẹ̀ Ẹ̀mí.”