Ọpẹ́ (Ẹ̀kọ́ 1)
3 min ka
0 Awọn asọye

Ọpẹ́ (Ẹ̀kọ́ 1)

Ọ̀RỌ̀ (Ẹ̀kọ́ 1): Ọgbọ́n Nínú Ìmoore Àwọn ẹsẹ Bíbélì: 1 Kíróníkà 29:10-22; 2 Kíróníkà 6:12-15; 7:1-3; 1 Tẹsalóníkà 5:15-18 . Ẹsẹ Iranti: “Ẹ maa dupẹ ninu ohun gbogbo: nitori eyi ni ifẹ Ọlọrun ninu Kristi Jesu nipa yin.” — 1 Tẹsalóníkà 5:18 .

Ka siwaju