ẸSẸ̀ ÌRÁNTÍ: Ẹ mã yọ̀ ni ireti; onísùúrù nínú ìpọ́njú; tẹsiwaju lojukanna ninu adura; Romu 12:12 ỌRỌ: Isaiah 60:1-3, Ẹksodu 29:1-21.
Ka siwajuÀWỌN ADÁJỌ́ FÚN IṢẸ́ ÌRẸ̀ ỌLỌ́RUN Ọ̀RỌ̀ ÌRÁNTÍ: Wura fun ohun elo wura, ati fadaka fun ohun fadaka, ati fun oniruru iṣẹ ti a fi ọwọ́ awọn oniṣọnà ṣe. tali o si fẹ lati yà iṣẹ-isin rẹ̀ si mimọ́ li oni fun Oluwa? 1 Kíróníkà 29:5
Ka siwaju